Thursday, January 10, 2013

Adùfẹ: Love Letter Written In Yoruba Language.
Adùfẹ…… owunmi lobìrin, oréké lé wà ọmọgé…mo nífé rè tori torùn, tèsè táyá, tojú, tẹ́nu 

Odùn lobìrin lá tokè dé ìsàlè. Tim bá tin ri ẹ áyá mi á ma ṣẹ gbìgbìgbì
Ọlọmọgé Ẹlẹjè tutu
Larìn awọ̀n ọmọ obìrin tí o wa layẹ yìí, iwo ni ọkàn mi yàn
To bá kọ̀ látì fẹ́ mi, mo má pá rá mi si ẹ lórùn
Wá ṣe temi..emi náà fẹ́ ṣe tí ẹ
Awọ̀n sisi pọ ni gbóró tí mo fí yan ẹ
odùn jú gbógbó cranberry juice layẹ yìí ati ọrún….

Adùfẹ baby mi… jọ́wọ̀ dákun ṣe temi…..babi yii jóò
mo fí ásíkọ yìí ṣélérí fún ẹ wípé nígbò jò, nígborùn, bí ìlẹ́ bán jó, bólẹ̀ bán já, tí ẹ ní mó má ṣé lojokojo

Ti ẹ ni tóòtọ
Ọkọ Adùfẹ

English Version
Adufe…a woman of my choice, beautiful young damsel. I love you from head to toe
Sweet lady from top to bottom. Whenever I set my eyes on you….my heart beats fast
Cool calm and collected beautiful damsel
Of all the women in the world, you are my hearts choice
If you fail to be with me, I can kill myself
Be mine, I want to be yours
There are many women in the world but i picked you
You are the sweetest juice ever
Baby please, be mine, please now,
I want to use this time to let you know that in all weather conditions and disasters, I’ll be yours at all time

Truly Yours
Adufe’s Boo

No comments:

Post a Comment

ST

Please Like Us On facebook