Showing posts with label Adùfẹ: Love Letter. Show all posts
Showing posts with label Adùfẹ: Love Letter. Show all posts

Thursday, January 10, 2013

Adùfẹ: Love Letter Written In Yoruba Language.
Adùfẹ…… owunmi lobìrin, oréké lé wà ọmọgé…mo nífé rè tori torùn, tèsè táyá, tojú, tẹ́nu 

Odùn lobìrin lá tokè dé ìsàlè. Tim bá tin ri ẹ áyá mi á ma ṣẹ gbìgbìgbì
Ọlọmọgé Ẹlẹjè tutu
Larìn awọ̀n ọmọ obìrin tí o wa layẹ yìí, iwo ni ọkàn mi yàn
To bá kọ̀ látì fẹ́ mi, mo má pá rá mi si ẹ lórùn
Wá ṣe temi..emi náà fẹ́ ṣe tí ẹ
Awọ̀n sisi pọ ni gbóró tí mo fí yan ẹ
odùn jú gbógbó cranberry juice layẹ yìí ati ọrún….

ST

Please Like Us On facebook